Awọn obinrin fariga, wọn ni asiko awọn lati ṣe Gomina ree, ki wọn fun Iyabọ Ọbasanjọ laaye nipinlẹ Ogun
Akinpelu Johnson
March 31, 2026
0
O fẹẹ jẹ pe ọrọ ibo Gomina fọdun 2027 nipinlẹ Ogun ti n gbọna mii yọ bayii nitori bawọn obinrin kan ṣe fariga pe gbogbo ọna law...
Read more »