Dare Olateju Adesope, aare fegbe OPC REFORMED fayeye ojoobi e sekilo - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

.com/img/a/
Coco Samba

Wednesday, 21 August 2019

demo-image

Dare Olateju Adesope, aare fegbe OPC REFORMED fayeye ojoobi e sekilo


opc
 
Okan lara awon omo Yoruba Atata ti ko se e fowo ro seyin ni Ambasedo Dare Olateju Adesope, odu ni kii saimo foloko ninu awon to n ja fun ilosiwaju ati idagbasoke ile Yoruba, oun ni Aare egbe OPC REFORMED.

 Oni ni okunrin naa sajoyo ojoobi e, nibi tawon elomin in ti fajoyo e sariya, ti won yoo maa nawo bi eleda, Oga OPC naa ko se bee, oun to so ni pe ilosiwaju ile Yoruba lo je oun logun, ati pe a ko gbodo pada si oko eru mo.

O so pe nnkan iwuri ni ki ojoobi eni soju eni, sugbon ki i se nnkan to bojumu ki eniyan ma dagba sinu agbegbe ati ayika ti ko wu ni lori rara.
 Nitori naa awon tiwon n se akoso ijoba wa lowolowo lo gba niyanju tori pe ki i se gbogbo eeyan lo ni oore ofe ko  maa dake bo ba ri nnkan ti ko to.

O ni ojo tipe tawon ti n pariwo lori redio atawon iwe iroyin pe ki awon oloselu se ilu daadaa sugbon egbe to ba ti n yin won nikan ni won feran, egbe to ba ti tako nnkan ti won n se, se ni won maa ri won gege bi egbe alatako, bee o ni awon o nii dake, ayafi bi won ba gbo. 

Dare tun fikun oro e pe se ni ki awon ijoba wa mojuto ojo iwaju awon odo, nitori pe awon ni ojo ola orile ede yii. O ni ominu maa ko oun, boun ba ri awon omokunrin to ye ki won wa lenu ise ki won maa kopa bi oro aje orileede yii yoo se ni ilosiwaju sugbon to je pe nidii ipate iwe iroyin(News papers stand) le ti maa ri won ti won maa bere ariyanjiyan to maa ja si ija lopo igba.

O ni kin ni odo fee maa pariwo ijangbara fun bi nnkan ba n lo deede? Eni to kan lo mo o nitori pe opo ni ko ri oinje je beeni ko ni ireti kankan sugbon tawon oloselu wa n gbadun bi eera suga!

Aare egbe OPC Reformed tun ni  orin bamubamu ni mo yo ni won nko, o ni bo ba doju e, oro Obafemi Awolowo Jeremiah yoo se o.

Nipa oro to n ja rainrain nipa ibudo fun eran osin awon eya fulani ti won so pe won fee da ruga sile ni ipinle kookan, o ni se awa ati fulani jo n sowo kan naa ni, bi won ba pa owo nibi ruga ta ni won maa ko fun? Se ni ki onikaluku se owo re lotooto ki a mo iye ti a fi pa o.ipinle kookan naa le ni ile osin eran tie,awon odo po niluu ti won ko ri se, o ni ki won dawon sibe ki won wulo fun ara won ati orile ede.
Ninu awon gomina ipinle ile Yoruba patapata,gomina ipinle Oyo nikan lo gbojugboya lati so pe oun ko faramo ruga,bi eyin gomina yooku ba faramo on,e ma gbagbe pe e si maa kuro ni ipo gomina, beeni Yoruba ki i gbagbe itan. Oba to je to ta ile wa fun eya miran, o ni oruko re ko nii pare laelae.

O wa kesi awon oba alade, pe ki won ma wo wa niran o. O ni
oju maa gba oun ti boun ba de oke okun, o ni awa naa le se ju bee lo sugbon ileri alagbada yii n ko.

No comments:

Post a Comment

Pages