Friday, 13 January 2023

Home
Unlabelled
Ẹgbẹ MAAN yan awọn oloye tuntun bẹẹ ni wọn tun da awọn kan duro
Ẹgbẹ MAAN yan awọn oloye tuntun bẹẹ ni wọn tun da awọn kan duro
Nibi ipade ẹgbẹ ọhun to waye ni ọfiisi wọn niluu Eko, ni wọn ti yan awọn oloye fidihẹ ọhun bẹẹ ni wọn tun da awọn kan duro fun igba diẹ, nitori aṣiṣe ti wọn ṣe, ti wọn fẹẹ fi maa ba ẹgbẹ naa loju jẹ.
Musibau, Alubarika Giwa, Surajudeen Amusa
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Je gbajumo oniroyin lorileede Naijiria, o ti ko ipa ribiribi lagboole iroyin, paapaa l'eka ede Yoruba.
No comments:
Post a Comment