Ọpẹ o! Iyawo Arẹms ọga oniroyin amuludun bimọ tuntun lonii - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

.com/img/a/
Coco Samba

Saturday, 22 April 2023

demo-image

Ọpẹ o! Iyawo Arẹms ọga oniroyin amuludun bimọ tuntun lonii

IMG_ORG_1682187336812


Idunnu lo ṣubu layọ fun idile agba ọjẹ oniroyin fun amuludun, Arẹmu Adeniyi, tọpọ mọ si Arems, iyawo ẹ lo bimọ ọkunrin lanti lanti lonii, ọjọ Abamẹta Satide.

Ninu atẹjade kan ti ọkunrin naa fi sita, lo ti dupẹ lọwọ Ọlọrun pe o jẹ ki iyawo oun sọ kalẹ layọ ati alaafia. To si fi akoko naa kede faraye pe ọmọ tuntun ti darapọ mọ ẹbi naa, ti gbogbo wọn si fo fayọ.

O sọ pe ọpẹ nla  lo jẹ fun ọkunrin ti iyawo ẹ ba bimọ layọ ati alaafia, nitori kinni naa ko rọrun, amọ ti Ọlọrun ko jẹ kawọn eeyan ba oun daro ibanujẹ, ti iya ati ọmọ naa si wa ni alaafia.

Arẹms sọ pe lakooko yii o, ọpẹ ṣaa ni, kawọn eeyan si maa ba oun dupẹ pẹlu.


No comments:

Post a Comment

Pages